Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 12: Irìn-àjò, Ibùdó àti Bíbéèrè znà > Lesson 4: Bí o bá f} lv sí ilé ìwòsàn Olúyoro




    

Bí o bá f} lv sí ilé ìwòsàn Olúyoro

Baba Olúf}mi:
Bí o bá f} lv sí ilé ìwòsàn Olúyoro, láti wo eyín tí ó n yv < l}nu.
O ní láti wv dánfó láti ìta wa níbí.
Sv fún oním<tò pé ò n lv sí iyànà ilé ìwòsàn Olúyoro tuntun.
Ogún naira ni owó vkz o, má j} kí w<n yàn jc}.
Tí o bá szkal| tán, fí cs| rìn bí i ìx}jú m}rin tààrà lórí òpóponá Tcjúm<lá,
Má yà s<tun, má sì yà sósì.
Orí títì yí ni wà á ti rí àwvn ilé ìtajà tuntun tí ìjvba ìbíl| Ibàdàn x|x| k< lápá ztún.
L}yìn àwvn ilé ìtajà yìí ni ilé ìwòsàn Olúyoro tuntun wà.
Kò tán síb|, tí o bá ti wv inú ilé ìwòsàn yí,
O ní láti rìn síwájú dí| kí o tó rí ilé alájà m}ta tí àwvn oníxègùn yvyínyvyín wà.
Yàrá tí ó k}yìn ní apá òsì ni òkè pátápátá ni oníxègùn yóó ti dá v lóhùn wa.