Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 13: IBÙGBÉ ÀTI ÌBÁGBÉPZ VMVNÌYÀN > Exercise 4:

Exercise 4:               Answer the following questions

        1. Níbo ni ilé tí Yétúndé rí wà?

        a. Nítòsí ilé-ìtàwé wvn
        b. Nítòsí ilé-ìwe wvn
        d. Nítòsí ilé-ix} wvn
        e. Nítòsí ilé-ijosin wvn
        c. Nítòsí ilé-cbí wvn
         
        2. Báwo ni yàrá Yétúndé tuntun xe f| tó?

        a. Ogun cs| ní òró àti ìbú
        b. Vgbzn cs| ní òró àti ìbú
        d. Árùndínlógún cs| ní òró àti ìbú
        e. Vg<ta cs| ní òró àti ìbú
        c. Ogójì cs| ní òró àti ìbú
         
        3. Ibùsùn mélòó ni yàra Yétúndé máa gbà?

        a. Ibùsùn kan àti àbz ni.
        b. Ibùsùn méjì xoxo ni.
        d. Ibùsùn kan xoxo ni.
        e. Ibùsùn kan péré ni.
        c. Ibùsùn méjì péré ni.
         
        4. Irú ètò aabò wo ni Yétúndé sv fún Ab<s|dé pé ilé r| tuntun ni?

        a. Ilé náà ni il|kùn gíga p|lú fèrèsé àti vgbà tí ó nípvn
        b. Ilé náà ní fèrèsé gíga p|lú il|kùn àti vgbà tí ó nípvn.
        d. Ilé náà ní vgbà gíga p|lú fèrèsé àti il|kùn tí ó nípvn.
        e. Ilé náà ní vgbà gíga p|lú il|kùn àti fèrèsé tí ó nípvn.
        c. Ilé náà ni il|kùn gíga p|lú vgbà àti fèrèsé tí ó nípvn
         
        5. Àwvn nnkan m}rin tí Yétúndé máa gbé sí yàrá r| tuntun ni:

        a. Àga, tábílì ikàwé, |rv amóhùnmáworán, àti rédíó
        b. Àga, tábílì oúnjc, |rv amóhùnmáworán, àti rédíó
        d. Àga, tábílì ikàwé, |rv amúnáwá, àti rédíó
        e. Àga, tábílì ikàwé, |rv amóhùnmáworán, àti àwòrán
        c. Àwòrán, tábílì ikàwé, |rv amóhùnmáworán, àti àga
         

© African Studies Institute, University of Georgia.