|
Lesson 2: Xé irú ilé yí ni o f} k<?
Fvláxadé: Adévlá, báwo ni?
Adévlá: Dáadáa ni, a dúp}.
Fvláxadé: Àwòrán wo ni ó wà ní vw< rc yì í.
Adévlá: Àwòrán ilé |gb<n mi ní ilú Am}ríkà ni
Fvláxadé: O dára púpz.
Xé irú ilé yí ni o f} k<?
Adévlá: O tì o.
Ilé tí mo f} máa j}
ilé alájà méjì tí yóò ni ilé igbókòsí nísàl|.
Fvláxadé: Xé iw< nìkan ni o f} gbé e ni tàbí o f} gba àwvn ayalégbé?
Adévlá: Èmi àti àwvn cbí mi níkàn ni.
Fvláxadé: Yàrá mélòó ni yóò wà níb|?
Adévlá: Yàrá márun ni mo f} kí ó wà níb|.
Fvláxadé: Báwo ni yó ò xe rí?
Adévlá: Yàrá kzzkan yò ó ní ilé-ìw| àti ilé ìgbzns|
Fvláxadé: Ibo ni c óo kó crù sí?
Adévlá: Yàrá kzzkan yoó ní k<b<zdù crù àti |rv amúlétutù.
Fvláxadé: Ibo ní c ó ti má a jcun àti gba at}gùn?
Adévlá: A ó ní yàrá nlá kan g}g} bí pálz.
Ilé ìdáná nlá má a wà ní ìsàl|,
A ó sì tún ní yàrá kan l}gbc r| fún ilé-ìjcun |
|