|
Lesson 4: Yàrá yìí yó ò bójúmu fún
ak}|k<
Yétúndé: Ab<s|dé, xé o ti rílé?
Ab<s|dé: B}| ni. Ìw< n k<?
Yétúndé: Mo x|x| f} lv sanwó yàrá kan nítòsí ilé-ìwé ni.
Ab<s|dé: O dára b}|
xùgb<n o gb<dz ri dájú pé ilé náà ní ètò aabò dáradára.
Yétúndé: Òót< lo
sv.
Ilé náà ní vgbà gíga p|lú il|kùn àti fèrèsé tí ó nípvn.
Ab<s|dé: Báwo ni yàrá náà xe f| tó?
Yétúndé: O mv ní ìwzn ogún cs| bàtá ní ìró àti
ibu.
Ab<s|dé: O f| gan an ni. Ibùsùn mélòó ni yóò gbà
Yétúndé: Ibùsùn kan xoxo ni.
Mo tún ní láti gbé àga àti tábílì ikàwé sí |gb} kan.
Ab<s|dé: Yàrá yìí yóò bójúmu fún ak}|k<.
Yétúndé: Mo til| tún máa gbé |rv
amóhùnmáworán àti rédíò sí |gb}
kan.
Ab<s|dé: Xé iná wà ní àdúgbò yí?
Yétúndé: Ó ní iná. Ó ní omi crz.
Wvn til| tún ní |rv amúnáwá nínu ilé náà.
Ab<s|dé: Ó tí lv wájú!
Wà Gbádùn ilé rc dáradára.
Yétúndé: B}| ni o.
|
|