Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 14:RÍRÀ ÀTI TÍTÀ > Lesson 2: Ríra òòt|c-l}tà ní ilé-ìfìwéránx}.




    

Ríra òòt|c-l}tà ní ilé-ìfìwéránx}.

Òxìx} ilé ìfìwéránx}: Ta ni ó kàn?!
Adéwálé:                         C káàárz.
Òxìx} ilé ìfìwéránx}:  Káàárz o, arákùnrin. Kí ni o f}?
Adéwálé: C jzw<, eélòó ni owó ìfìwéránx} lv sí ìlu Tógò?
Òxìx} ilé ìfìwéránx}: Irinwó náírà ni. L}tà mélòó ni o f} fi ráns}?
Adéwálé: L}tà kan yìí náà ni. Òxìx} ilé ìfìwéránx}: O dára. Kí ni ó tún kù?
Adéwálé: Mo f} ra òòt|c-l}tà Òxìx} ilé ìfìwéránx}: Òòt|c-l}tà mélòó?
Adéwálé: Èlèèló ni àwvn òòt|c-l}tà tí c ni?
Òxìx} ilé ìfìwéránx}: Arákùnrin, iye tí o bá f} ni kí o sv. Gbogbo òòt|c-l}tà ní a ní.
                    A ní ti ààd<ta náírà, ti vg<rùn-ún náírà, igba náírà àti
                    ti ||d}gb|ta náírà.
Adéwálé: C jzw<, c fún mi ní vlóg<rùn-ún náírà méjì àti onígba naira kan.
Òxìx} ilé ìfìwéránx}: Òun nìyí. Àpapz owó rc j} cgb|rún náírà.
Adéwálé: C xe púpz. O dàbz.