Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 14: ÒNKA YORÙBÁ > Lesson 3: Idásíw}w} àti Idá-àpò (Fractions and Percentages).
    

 Ìdásíw}w} àti  Ìdá-àpò (Fractions and Percentages) 

Idásíw}w}:
½ :    Ìdáméjì / Ìdajì 1/3:    Ìdám}ta / Ìdata
¼ :    Ìdám}rin / Ìdarin 1/5:    Ìdámárùnún / Ìdarùn-ún
1/6 :    Ìdám}fa 1/7:    Ìdaje
1/8:     Ìdám}jz 1/9:    Ìdasàn-án
1/10:   Ìdám}wàá                     àti b}|b}| lv.
 

- Formation of all other fractions:

Rule:  ìdá + denominator (cardinal form) l<nà numerator as in:
3/5:    ìdá + márùn l<nà m}ta    =    ìdámárùn l<nà m}ta
2/3:    ìdám}ta l<nà méjì    2/5:   ìdámárùnún l<nà méjì
4/5:    ìdámárùn l<nà m}rin    5/7:   ìdáméje l<nà márùn-ún
3/10:    ìdám}wa l<nà m}tà              àti b}|b}| lv.
 

Idá-àpò:

100%    ìdá-àpò vg<rùn     50%     ìdá-àpò aádztá
25%     ìdá-àpò m}cd<qzn     10%     ìdá-àpò m}wàá
5%      ìdá-àpò márùn-ún       1%      ìdá-àpò kan
 
- Formation of all other percentages:
Rule:     ìdá-àpò cardinal form as in:
11%     ìdá-àpò m<kànlá     15%      ìdá-àpò m}cdógún
19%   ìdá-àpò m<kàndínlógún     65%    ìdá-àpò márùndínláàd<rin
86%    ìdá-àpò m}rindínláàd<run 99%  ìdá-àpò m<kàndínl<g<run

 

 

 

© African Studies Institute, University of Georgia.