|
A
f} ra epo pupa àti
iyz.
Adélékè àti Àbík}: C káàsán o, ìyá alátc.
Ì yá Alátc: C káàsán o. X’álàáfíà ni?
Adélékè àti Àbík}: A dúp} o. Xé ajé n
wvgbá?
Ìyá Alátc: A dúp}. Kí ni c f} rà?
Adélékè: A fé ra epo pupa àti
iyz.
Àbík}: Epo pupa ìgò kan àti zrá iyz méjì
Ìyá Alátc: Náírà m}wàá ni ìgò epo pupa.
Adélékè: iyz n k<?
Ìyá Alátc: Náírà m}ta ní zrá kzzkan.
Àbík}: Gbogbo r| j} náírà m}rìndínlógún, àbí?
Ìyá Alátc: B}|ni, epo pupa ìgò kan àti zrá iyz méjì j} náírà m}rìndínlógún
Àbík}: Adélékè, sanwó!
Adélékè: Owó nì yí. C gbà.
Ìyá Alátc: Ajé yín o.
Adélékè àti Àbík}: Ó dàbz.
|
© African Studies
Institute, University of Georgia.
|
|