|
Báyìí ni Yorùbá xe n pín vj<.
Olùk<: C kúux} o, |yin ak}kz<.
Àwvn Ak}kz<: O o o ò.
Olùk<: Nígbàwo
sí ìgbàwo ni à lè pè ní àárz?
Fvláxadé: Nnkan bí aago márùn-ún sí aago méjìlá ku ìx}jú kan.
Olùk<: B}|
ni, o gba a. Táíwò, nígbàwo sí ìgbàwo
lzsán?
Taiwo: Nnkan
bí aago méjìlá sí aago márùn-ún ku ìx}jú kan.
Olùk<: O káre, b}| ni. Nígbàwo sí ìgbàwo
wá nìrzl|, Dayz?
Dayz: Aago
márùnún sí nnkan bí aago méje àbz.
Olùk<: Lóòót< ni. Al} wá n k<?
Dayz: Aago
m}jv títí di aago m<kànlá ku ìs}jú kan.
Olùk<: Xé c mv ìgbà tí à n pè ní òru? Dayv
ati Taiwo: B}| ni, a mz <.
Oru
ni igba ti gbogbo eniyan ba
ti sun.
Olùk<: B}| ni.
Aago méjìlá títí di bí i aago márùn-ún àárz ni òru.
Fvlásadé: Nigbawo wa ni aarv kùtùkùtù?
Olùk<: Vw< aago
márùn-ún àárz si bí i aago m}fà àbz tí àwvn
ènìyàn
tó sùn bá n jí, ni àárz
kùtùkùtù tàbí àf|júm<.
Fvlásadé: Há. Ó ti yé mi dáradára báyìí.
Olùk<: Mo lérò pé ó ti yé gbogbo wa. Àárz, zsán,
ìrzl} àti
al}, Báyì í ni Yorùbá xe n pín vj<
|