1

Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 15:Ix} yìí kò wù mí xe rárá > Exercise 1:

EXERCISE 1:  Review Lesson 1 and state whether these statements about
  Gbémis<lá and her father are true or false (Lóòót< ni tabi Lóòót< k<):


1. Bàba Gbémis<lá kò ì di zgá lcnu ix} vl<pàá. Lóòót< ni Lóòót< k<
2. Baba Gbémis<lá ní ìbvn kan tí ó máa n fi pam< sínú vkz r} Lóòót< ni Lóòót< k<
3. Gbémis<lá mv zpzlvpz ìlú ní orílé-èdè Nàìjíríyà nítorí pé bàbá r| ti xix} ní àwvn ìlú yìí. Lóòót< ni Lóòót< k<
4. Bàba Gbémis<lá ti n xe ix} vl<pàá fún vdún m}|dógún Lóòót< ni Lóòót< k<
5. Bàbá Gbémis<lá ní vkz ìjvba tí w<n n wà àti vl<pàá m}rin tí wvn n x< ilé wvn. Lóòót< ni Lóòót< k<
6. Ní cnu ix} yìí, Bàbá Gbémis<lá ti xix} ni |ka ztcl|múy}, |ka ìrìnnà oko àti ilé |k< àwvn vl<pàá. Lóòót< ni Lóòót< k<
7. Ix} vl<pàá kò wù Gbémis<lá xe rárá Lóòót< ni Lóòót< k<
8. Ix} vl<pàá kò ní ewu rárá, ó sì ní owó lórí púpz Lóòót< ni Lóòót< k<
9. Zpzlvpz àwvn vl<pa ni àwvn adigunjalé ti pa Lóòót< ni Lóòót< k<
10. Màmá Gbémis<lá wà nínu cgb} àwvn ìyàwó zgá vl<pa Lóòót< ni Lóòót< k<


© African Studies Institute, University of Georgia.