Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 15: Ix} j< > Lesson 1: Ix} y k w m xe rr
    

Ix} y k w m xe rr
Gbémis<lá: Ix} vl<pa ni bàbá mi n xe. Vdún m}|d<gbzn nì yí tí bàbá mi ti n xe ix} yìí. W<n ti di zgá báyìí. Àwvn ni igbákejì olórí àwvn vl<pa ní ìpínl| Ògùn. Bárìkì zgá àwvn vl<pa ni à n gbé. Baba mi ti xix} ní zpzlvpz |ka kí w<n tó di zga báyìí. W<n ti xix} ní |ka ìrìnnà oko. W<n ti xix} ní |ka ztcl|múy} W<n sì ti xix} ní ilé |k< àwvn vl<pá. Mo mv zpzlvpz ìlú ní orílé-èdè Nàìjíríyà nítorí pé bàbá mi ti xix} ní àwvn ìlú yìí. Nísisìyí, bàbá mi ní vkz ìjvba tí w<n n wà. W<n ní vl<pa m}rin tí ó n x< ilé wa. Cnìkan n t|lc wvn ní gbogbo ibi tí w<n bá n lv. Cnìkan j} awàkz fùn wvn. Cnìkan ma n fv axv wvn. Zpz àwvn vl<pa ni ó ma n b}rí fún bàbá mi. Baba mi náà má n b}rí fún àwvn tí ó jù w<n lv l}nu ix}. Baba mi ní ìbvn méjì. W<n ma n so zkan m< |gb}. W<n sì fi èkejì pam< sínú ilé wa. Màmá mi wà nínu cgb} àwvn ìyàwó zgá vl<pa. Ix} tí ó léwu ni ix} yìí. Zpzlvpz àwvn vl<pa ni àwvn adigunjalè ti pa. Bí ix} yìí ti léwu tó, kò ní owó lórí rárá. Owó oxù àwvn vl<pa kò pz rárá. N kò le xe ix} g}g} bí ix} òòj< mi. Ix} yìí kò wù mí xe rárá.