|
Lesson 3: Tí mo bá parí ilé ìwé mi.
Múyiwá: Káàsán, xe dáadáa ni?
Kóredé: Dáadáa ni, a dúp}.
Múyiwá: Irú ix} wo ni o f} xe tí o bá dàgbà?
Kóredé: Ix} àgb| ni mo f} xe.
Múyiwá: Oríxiríxi àgb| ni ó wà. Èwo ni ó wù ó?
Xé àgb| aládìyc ni tàbí cl}ja, tàbí eléso, tàbí olóhun zgbìn?
Kóredé: Ó wù mí láti xe ix} àgb| aládìyc àti olóhun zgbìn
Múyiwá: Irú àwvn ohun zgbìn wo ni ó wù ó láti gbìn?
Kóredé: Awvn ohun zgbìn bíi ege, |wà, ixu, àgbàdo àti b}| b}| lv.
Múyiwá: Báwo ni o ti f} xe ti adìyc?
Kóredé: Cgb} oko yìí ni vgbà adìyc yóò wà.
Ìgb} àwvn adìyc yìí yoo je àjílé fún àwvn ohun zgbìn mi.
Múyiwá:: Àwvn wo ni ó maá ta ohun zgbìn yìí fún?
Kóredé: Àwvn m|kúnnù ni yóò wù mí láti tà á fún
Múyiwá: Xé b}| ni wà á xe fún adìyc náà?
Kóredé: Àwvn ilé-ix} nlánlá ni yóò má a wá kó cyin l<szzs|.
Múyiwá: O ti ro gbogbo r| dáadáa.
Vl<run á j} kí o lè xe ix} yí o.
Kóredé: Àmín àxc. C xé púpz.
Kí Vl<run j} kí ó rí b}|. |