Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 5: Ix} Òòj< > Lesson 5: Ix} Olùk<




    

 Ixc Olùk< j} zkan lára àwvn ix} oòj< tí ó xe pàtàkì jùlv. Olùk< ni àwvn tí ó n k< vmv ní |k< ní ilé-ìwé. Oríxiríxi olùk< ni ó sì wà. A ní olùk< ilé-ìwé alákvb|r|, a ní olùk< ilé-`iwé gírámà, a ní olùk< ilé-ìwé olùkvni, a sì tún ní olùk< ti Yunifásítì. Zpz lára àwvn olùk< ilé ìwé olùkoni àti Yunifásítì ni w Vkùnrin àti obìnrin ni ó lè xe ix} olùk<.
Cni tí ó bá f} xix} olùk< lè lv sí ilé |k< olùk< l}yìn ilé-|k< gírámà. Vdún m}tà ni yóò lò láti gba oyè En-siì. Tí ó bá f}, onítzhún tún lè lv sí Yunifasítì l}yìn En-sií láti lo vdún m}ta míràn. Yàtz sí èyí, enìyàn náà lè lv sí Yunifásítì tààràtà láti kv ix} olùkvni. Vdún m}rin ni yóò lò. Zpzlvpz |kà-|k< ni ó wà tí olùk< lè k< m< |k<. Lára wvn ni |k< nípa èdekède tí enìyàn bá fc. Àpccrc àwvn |k< míràn ni |k< nípa ìxírò, sáy}nsì, ìtàn àti b}| b}| lv.
Ix} olùkvni kò lówó lórí púpz, xùgbiyì ní àwùjv. Zpzlvpz vmv tí olúk< ti k< rí ni ó ti di zgá láwùjv. Kò sí cni tí olùk< kò k< rí láti ológun, panápaná, òxèlú, vlapòògùn, dvkàn enìyàn bal| láwùjv, ó sì xe pàtàkì púpz púpz.