Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 5: Ix} Òòj< > Lesson 6: O ti b|r| Ix} D<kítà nìycn!




    

O ti b|r| Ix} D<kítà nìycn!

Màmá ìbejì:               C káàsan d<kítà.
D<kítà Adéoyè:        C káàsan mama ìbejì
Màmá ìbejì:             C jzw<, báwo ni enìyàn xe lè k< ix} yín?
D<kítà Adéoyè:        Vm< ní láti lv sí yunifásítì fún vdún m}fà sí méje
                                       l}yìn ilé-ìwé gírámà.
Màmá ìbejì:               Kí ni yóò ma a xe fún vdún méje?
D<kítà Adéoyè:        Yóò ma k< |k< nípa sáy|nsì, |k< nípa ará enìyàn àti b}| b}| lv.
Màmá ìbejì:               Tí o bá parí n k<?
D<kítà Adéoyè:        Yóò lo vdún kan ní ilé ìwòsán láti fojúsí àwvn àgbà oníx|gùn
Màmá ìbejì:               L}yìn èyí xé ó ti di d<kítà nìycn?
D<kítà Adéoyè:        B}| ni , xùgb<n ó gbvdz lv xe agúnbániró fún vdún kan.
                                      L}yìn èyí , ó ti b|r| ix} d<kítà nìycn!
Màmá ìbejì:               Ó dára. Nj} gbogbo aláìsàn ni yóó lè yanjú?
D<kítà Adéoyè:        Rárá o. Ó tún ní láti k< |k< si láti lè t<jú aláìsàn tí ó bá wu ú.
Màmá ìbejì:               Ohun tí | n sv kò yé mi?
D<kítà Adéoyè:        Oríxii |kà ìxègùn ni ó wà. Vmv náà lè pinnú láti k< |k< nípa ìt<jú                                               àwvn vmvdé, ìt<jú aláboyún, ìt<jù alárun vpvlv, ìt<jú imú àti zfun tàbí                                        oríxii |k< ìlera míràn.
Màmá ìbejì:                Á j} pé ix} pz tí àwvn vmv mi yóò xe.
D<kítà Adéoyè:        B}| ni o, àwon vmv tí ó bá f} di oníx|gùn gbvdz múra sí |k< wvn.