2

Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 16:Ètò Ck< ní ìlu Nàìjíríyà > Exercise 2:

Exercise 2:     Review Ogunjimi’s description of Nigeria’s Educational system in
Lesson 2 and state whether these statements are True or False (Lóòót< ni / Lóòót< k<)


1. Ìlànà ètò ck< ní ìlu Nàìjíríyà ní ètò fún gbogbo ak}kz< láti j}léósinmi títí dé yunifásítì. Lóòót< ni Lóòót< k<
2. Ìjvba àti àwvn òbí kò pa vw< pz mójútó |k< àwvn vmvdé. Lóòót< ni Lóòót< k<
3. Ètò àdáxe ni ilé ìwé j}léósinmi láárin àwvn òbí àti olùk<. Lóòót< ni Lóòót< k<
4. Nísìsìyí, ìjvba ti kàn án nípa pé gbogbo vmv ni ó gbvdz lv sí ilé ìwé alákvb|r|. Lóòót< ni Lóòót< k<
5. Ilé ìwé alákvb|r| k< ni vmv máa lv l}yin j}léósinmi. Lóòót< ni Lóòót< k<
6. Ní àpapz, vdún m}fà ni ak}kz< máa lò ní ilé |k< gírámà kékeré àti ilé |k< gírámà àgbà. Lóòót< ni Lóòót< k<
7. L}yin gírámà kékeré, cní bá fc lv k< ix} vw< lè gba ib| lv sí ilé |k< ìk<x} vw<. Lóòót< ni Lóòót< k<
8. Àwvn tí ó ba parí gírámà àgbà lè gba ib| lv sí Yunifásítì fún oyè ìjìnl|. Lóòót< ni Lóòót< k<
9. Ilé |k< j}léósinmi k< ni ilé ìwé àk<k< fún àwvn vmvdé. Lóòót< ni Lóòót< k<
10. Ìlànà ètò |k< ní ìlu Nàìjíríyà dára nítorípé ó ní ètò fún gbogbo ak}kz<. Lóòót< ni Lóòót< k<


© African Studies Institute, University of Georgia.