Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 16: t Ck< > Lesson 2: t Ck< n lu Njry.
    

t Ck< n lu Njry.
Ògúnjìmí: Ìlànà fún ètò ck< ní ìlu Nàìjíríyà dára púpz.
O ní ètò fún gbogbo ak}kz< láti j}léósinmi títí dé yunifásítì.
Yàtz sí wipe àwvn ilé ck< wà ní ìgbésè n t}l|, Ìjvba àti àwvn òbí n pa vw< pz mójútó |k< àwvn vmvdé. Ilé |k< j}léósinmi ni ilé ìwé àk<k< fún àwvn vmvdé.
Ètò àdáxe ni èyí láárin àwvn òbí àti olùk< j}léósinmi.
Ìjvba
kì í l<w< púpz sí ètò |k< ní |kà yí.
L}yin j}léósinmi ni ilé ìwé alákvb|r| vl<dún m}fà.
Nísìsìyí, ìjvba ti kàn án nípa pé gbogbo vmv ni ó gbvdz lv sí ilé ìwé alákvb|r|.
Ní ìparí vdún m}fà, ilé |k< gírámà ni ó tún kàn fún vdún m}fà. Vdún m}ta ni ilé |k< gírámà kékeré àti vdún m}ta ni ilé |k< gírámà àgbà. L}yin gírámà kékeré, cní bá fc lv k< ix} vw<} lè gba ib| lv sí ilé |k< ìk<x} vw<. Àwvn tí ó ba parí gírámà àgbà lè gba ib| lv sí Yunifásítì fún òye ìjinl|. Àwvn míràn sì lè lv sí ilé |k< àwvn olùk< àgbà láti gba ìwé |rí àwvn olùk<.