|
Ilé ìwé rc tuntun yí dára gbá à.
Dàda: Káyzdé, xe ò n gbádùn ilé-ìwé rc tuntun?
Káyzdé: B}| ni |gb<n mi, mò n Gbádùn r|.
Dàda: Báwo ni ilé-ìwé rc tuntun yìí xe rí?
Káyzdé: Ó dára púpz. Ak}|k< bí cgb|rún m}wàá ni ó wà níb|.
W<n tún ní àwvn olùk< bíi z<dúnrún.
Dàda: Ó tóbi dí| o. Ilé-ìwé tiwa kò ní ju cgb}run m}fà lv.
Àwvn olùk< tiwa kò sì ju igbá lv.
Káyzdé: Xé c mz pé àtvkùnrin àtobìnrin ni ó wà ní ilé ìwé tiwa.
Dàda: Nítòót<, okùnrin nìkan ni ó wà ní ilé ìwé tiwa.
G}g} bí ilé ìwé aládání, kò sí ak}|k< kankan tí ó n gbé inú vgbà.
Ilé ni gbogbo wá ti n wá.
Káyzdé: Ilé |k< ìjvba àpapz ni ilé ìwé mi tuntun nítorí náà gbogbo
àwa ak}|k< ni ó pvn dandan fún láti gbé inú vgbà ilé-ìwé.
A tún ní gbógan nlá tí ó tóbi àti papa ìxeré ìdárayá tí ó f| gan.
Dàda: Àwa náà ní gbógan nlá, xùgb<n a kò ní papa ìxeré ìdárayá
Ilé ìwé rc tuntun yí dára gbá à.
Xé o máà b|r| sí gbé nínu vgbà nìycn?
Káyzdé: B}| ni o.
|