Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 16: Ètò Ck< > Lesson 4: Àwvn Oríxiríxi Ìwé-Crí àti Oyè Ck<




    

Àwvn Oríxiríxi Ìwé-Crí àti Oyè Ck<

Ède Yorùbá

English

Ìwé-|rí alákvb|r|

Primary School Leaving Certificate   

Ìwé-|rí oníwe-m}wàá

Secondary School Certificate / WASC

Jí-si-ìi oniígbés| kinní

GCE (Ordinary Level)

Ji-si-ii onígbés| kejì

GCE (Advanced Level)

Ìwé-|rí ck<xe

Trade or technical training Certificate

Ìwé-|rí olùk< onípòkejì

Teacher’s Training Certificate

Ìwé-|rí àwvn Olùk< onípò-kcta

Grade III Teachers Certificate

Ìwé-|rí àwvn Olùk< onípò-kejì

Grade II Teachers Certificate

Ìwé-|rí àwvn Olùk< onipo-kinni

Grade I Teachers Certificate

Ìwé-|rí Cn-Siii

Nigeria Certificate in Education (N.C.E)

Ìwé-|rí Ck< Gbogbo Nxe

Ordinary National Diploma (OND)

Ìwé-|rí Ck< Gbogbo Nxe Àgbà

Higher National Diploma (HND)

Ìwé-|rí Asoso

Certificate in Education (Ass. degree)         

Oyè Àk<k< nínú ìmv ìpìl|-|dá /    Bí-Eè

Bachelor of Arts (B.A)

Oyè Àk<k< nínú ìmv-|k< / Bí-Iidì

Bachelor of Education (B.Ed.)

Oyè Àk<k< nínú ìmv-sáy}nsì /      Bi-Ccsi

Bachelor of Science (B.Sc.)

Oyè ìjinl|/Cm Ee/ Cm Eesii / Cm Fii

Masters Degree /M.A. /M.Sc. /M.Phil

Oyè ìjinl| gíga

Doctor of Philosophy (Ph.D.)