Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 16: Ètò Ck< > Lesson 5: Ck< Ilé náà xe pàtàkì




    

Lesson 5:       Ck< Ilé náà xe pàtàkì
Ìyá Àgbà: 
Zpzlvpz àwvn vmv ní òde òní ni kò ní |k< ilé rárá. Àwvn òbí wvn náà kò sì gbìyànjú àti k< wvn dádáa. Ohun tí ó jc w<n lógún ni kí àwvn wznyí xe dáadáa ní ilé |k<. W<n ti gbàgbé pé |k< ilé náà xe pàtàkì. Ní il| Yorùbá, ìwà vmvlúwàbí ni ìt<ka cni tí w<n k<, tí ó sì gba |k< ilé. Vmvlúwàbí yóò wùwà tó bójúmu nínu ilé àti lode, kò sì ní fojúdì cnik}ni. Kò yé zpz àwvn òbí ìwòyí pé ojúxe wvn ni láti k< àwvn vmv wvn ní |k< ilé. W<n gbvdz mz pé nípax| àlàyé xíxe, ìbáwí, ìmzràn gbígbà àti àpccrc tó jvjú, àwvn vmv wvn yóò dàgbà di enìyàn rere láwùjv. Abiiko ní zpz w<n tí w<n dàgbà di akoogba. Oríxi àwvn èkó kéékèé ni zpz àwvn vmv ní àdúgbò wa níbí yi kò mz rárá. W<n ó léko bí a xe n kí enìyàn tàbí bí vmvdé xe gbvdz xe ayesí àgbàlagbà. Púpz nínu wvn kò ní òye wipe vmvkùnrin gbvdz dzbál|, kí vmvbìnrin sì kúnl| kí àwvn àgbà ní àárz kùtùkùtù. Wvn ò mz wipe vmvdé ni ó gbvdz k<k< kí àgbàlagbà ní gbogbo ibi tí ó bá ti rí wvn. Kódà, wvn á rí v p|lú crù, w<n ó sì máa lv. Wvn ò mz pé vmvdé gbvdz gba crù l<w< àgbà tàbí kí ó gba ohun tí w<n mú l<w< níbi tí ó bá ti pàdé wvn.

APEERE AWON EKO ILE TI O SE PATAKI
APEERE AWON EKO ILE TI O SE PATAKI
- Vmvdé gbvdz gb<ràn sí àwvn òbí àti àgbàlagbà l}nu – ó ní láti gb< gbogbo àlàyé àti ìmzràn wvn. Ó sì gbvdz k<gb<n nínu gbogbo ìbáwí wvn.
- Vmvdé gbvdz kí àwvn àgbàlagbà ní àárz kùtùkùtù àti nígbàkigbà tí ó bá rí wvn:
Vmvkùnrin gbvdz dzbál|, kí vmvbìnrin sì kúnl|.
- Vmvdé kò gbvdz pe àwvn tí ó bá ju lv ní orúkv.
- Vmvdé kò gbvdz dá sí zrz tí àwvn àgbà bá n sv. À fi tí w<n bá ní kí ó dá si.
- Vmvdé gbvdz ycra (ó gbvdz dìde ní àárín wvn) níbi tí àwvn àgbàlagbà bá tí n szrz
- Vmvdé gbvdz gba crù lórí àgbàlagbà
- Vmvdé kò gbvdz fi vw< òsì fún àgbàlagbà ní nnkan
- Vmvdé bá jí ní àárz, ó gbvdz k<k< xe ix} ilé tí w<n bá yàn fun (bí i gbígbá il| inú ilé, fífv gbogbo ab< tí ó bá dztí tàbí pípvn omi wvlé láti odò)
- Vmvdé ní láti mv àwvn oríxi eèwz tí ó gbvdz pam<. Èèwz bí i:
            a. A kì í jóko lórí odó
            b. A kì í jóko jcun l}nu znà
            d. A kìí  fi vw< kó ìdztí
            d. A kì í súfe lál} tàbí lóru.