Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 16: t Ck< > Lesson 6: rr mi n Grj Vj
    

Ìrírí mi ní Gárájì Vj<ta

Ohun tí mo rí ní zs| tí ó kvjá yà mí l}nu púpz. Mo rin ìrìn àjò lv sí ìlú Ìbàdàn. L}yìn tí mo ti jóko sí inú vkz ní Vj<ta, bàbá kan wvlé jóko sí |yìn mi. Vmvdébìnrin kan náà tún wvlé sí |yìn mi. Nígbà tí ó f} jókòó, vmvdébìnrin yí fi bàtà tc bàbá tí ó jóko l}s|. Baba yí kígbe nítorí tít|m<l| yí dùn ún gán-an ni. Vmvbìnrin yìí kò kí bàbá yìí rárá. Ó b|r| sìí bú bàbá yìí pé ó n pariwo. Àwa èrò yókù sì n kí bàbá yìí. Cnìkan fi òrí pa ibi tí ó n dun bàbá yìí. Àwa èrò n szrz sí vmvbìnrin yìí pé kò ní |k<-ilé ni. Cnìkan til| ní bóyá àbíìkz ni. Ó ní àwvn òbí r| kò kv bí a ti n bzwz fún àgbà ní àwùjv. Cnìkan tún sv pé bóyá w<n kv xùgb<n tí kò gba |k<. Vmvbìnrin yìí kò dák}. Ó n bú gbogbo cni tí ó n szrz si. Báyìí ni cnìkan fvw< tv ní èjìká pé kí ó dák}. Xe ni ó gbá vw< mama yìí dànù. Màmá yìí sì dàgbà tó cni tí ó lè bí l<mv. Báyìí ni agbèrò vkz b|r| síí bu. Òun naà sì n bú agbèrò. W<n n bú ara wvn. Agbèrò sì sv fun pé òun kò ní j} kí ó wv vkz náà. A lérò pé yóò bc agbèrò ni xùgb<n kò xe eléyi. Ó n m< gbogbo enìyàn lójú. Ó gbé crù r} nínu vkz ó sì sz. Ìwà vmvbìnrin náà yà mí l}nu púpz. Ó j} aláìl}kz vmv, kìí  xe vmvlúwàbí rárá.