Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 17: Awvn vl<pàá n wá àwvn adigunjalè mcrin > Exercise 3:

Exercise 2:               Answer the following questions

        1. Kí ló dé tí Oloye Makinde n xe ìnáwó n lá l<j< tí a n ròyìn yí?

        A. a. Wvn n xí ilé tuntun
         
        B. b. Wvn n sv vmv lórúkv
         
        D. d. Wvn n fi vmv f<kv.
         
         
        2. Níbo ni àwvn cbí àti zrc vkv ti wá dáná?

        A. a. W<n wá láti Ogbómzs<
         
        B. b. W<n wá láti Akínmz<rìn
         
        D. d. W<n wá láti Af}nif}re
         
         
        3. Kíni àwvn oúnjc m}r}|rin tí w<n xètò níbi ìgbeyàwó yìí?

        A. a. Iyán, vkà, ìrcsì àti láfún
         
        B. b. Iyán, àmàlà, |wà àti láfún
         
        D. d. Boli, epa, isu, ati dundun
         
         
        4. Màálù mélòó ni wvn pa ní vj< àxeyc yìí?

        A. a. W<n pa màálù m}fà
         
        B. b. W<n pa màálù márùn-ún
         
        D. d. W<n pa màálù m}rin
         
         
        5. Yàtz sí màálù àti cja tútù, irú cran wo ni w<n tún sè?

        A. a. W<n se adìyc, ògúnfe, panla, cran ìgb} àti ìgbín díndín
         
        B. b. W<n se adìyc, màálù, tòlótòló, p}p}yc àti ògúnfe
         
        D. d. W<n se adìyc, cran ìgb}, cl}d|, akàn àti ìgbín sísè
         
         
        6. Cgb} wo ni o tún pèsè |f< rírò p|lú edé àti cja gbígbc?

        A. a. Cgb} ìyàwó
         
        B. b. Cgb} vkv
         
        D. d. Cgb} Olóyè Mákindé
         
         
        7. Kíni Olóyè Mákindé kó sínú àwvn Àgbá nlá tí w<n gbà láti Owódé?

        A. a. Ohun jije
         
        B. b. Ohun sise
         
        D. d. Ohun mimu
         
         
        8. Ní ìlú wv ni Olóyè Oyèwálé Mákindé ti jc oyè e Gb<baníyì?

        A. a. W<n j} Gb<baníyì ti ìlu Fìdítì
         
        B. b. W<n j} Gb<baníyì ti ìlu Jóbèlè
         
        D. d. W<n j} Gb<baníyì ti ìlu Akínmz<rìn
         
         

 

© African Studies Institute, University of Georgia.