Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 17: Awvn vl<pàá n wá àwvn adigunjalè mcrin > Exercise 4:

Exercise 4:      Review Lesson 4 and select the best answer for the following questions from the list provided:

        1. Ìlú wo ni àdúgbò Tèmídire wà?

        a. Ó wà ní Ìlu Ìyìn Èkìtì
        b. Ó wà ní Ìlu Adó Èkìtì
        d. Ó wà ní Ìlu Ìfàkì Èkìtì
        e. Ó wà ní Ìlu Ìkzlé Èkìtì
        c. Ó wà ní Ìlu Àkókó Èkìtì
         
        2. Agbo ilé bí i mélòó ni ó wà ní àdúgbò Tèmídire?

        a. Agbo ilé bí i méjì
        b. Agbo ilé bí i méjìdínlógójì
        d. Agbo ilé bí i ogójì
        e. Agbo ilé bí i àádójì
        c. Agbo ilé bí i ogún
         
        3. Yàtz sí m<xáláxí, irú àwvn ilé-ìj<sìn wo ni ó wà ní àdúgbò Tèmídire?

        a. Ilé-ìj<sìn àw<n onít|bvmi àti tàwvn Aj}rìí Jìhófà
        b. Ilé-ìj<sìn Àgùdà àti tàwvn telétò
        d. Ilé-ìj<sìn Kérúbù àti Séráfù
        e. Ilé-ìj<sìn ijo mimo lati orun wa ati Apostoliki
        c. Ilé-ìj<sìn awon alatewo ati Ajeri jah jihofa
         
        4. Kí lódé tí àdúgbò Tèmídire kò ní ilé vl<pàá?

        a. Nítorí wípé kò sì àwvn adigunjalè àti adáj<
        b. Nítorí wípé àwvn adigunjalè àti zdaràn ti pzjù.
        d. Nítorí wípé kò sì àwvn vl<pàá ní àdúgbò Tèmídire
        e. Nítorí wípé kò sì àwvn adigunjalè àti zdaràn rárá
        c. Nítorí wípé kò sì àwvn adigunjalè àti zdaràn púpz
         
        5. Báwo ni àwvn cbí kzzkan ní àdúgbò Tèmídire xe n rí omi?

        a. W<n máa n ra omi |rv ní iwájú ilé wvn
        b. W<n máa n pvn omi odò ní iwájú ilé wvn
        d W<n máa n gb<n omi ìbùl| ní iwájú ilé wvn
        e. W<n gb} kànga sí inú ilé kzzkan
        c. W<n gb} kànga sí iwájú ilé wvn
         
        6. Gómìnà wo ni w<n yàn lati àdúgbò Tèmídire?

        a. Gómínà ìpínl| Èkìtì tí ó n bz.
        b. Gómínà ìpínl| Èkìtì tí ó kvjá.
        d. Gómínà àdúgbò Tèmídire,
        e. Gómínà Adéwálé Dàda
        c. Gómínà ìpínl| Èkìtì tuntun
         

© African Studies Institute, University of Georgia.