Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 17: ÌMÚNI MVNI > Exercise 5:

Review Lesson 5 and choose whether these statements are True or False (Lóòót< ni tàbí Lóòót< k<):


1. Ààyè kò sí fún àwvn obìnrin láti xe zpzlvpz ix} òòjó nínú àxà ìbíl| Yorùbá Lóòót< ni Lóòót< k<
2. Awvn Yorùbá kò gbàgb< pé ìpín àwvn obìnrin ni láti jókó sílé láì xix}. Lóòót< ni Lóòót< k<
3. Àwvn Yorùbá kò gbàgb< pé àwvn obìnrin lè xe àwvn ix} alágbára oríxiríxi bíi ix} vdc àti ix} ológun. Lóòót< ni Lóòót< k<
4. Àwvn obìnrin Yorùbá kò ní oríxii ix} tí w<n maá n xe g}g} bí ix| òòj<. Lóòót< ni Lóòót< k<
5. Kódà (in fact), àwvn obìnrin nínú àxa ìbíl| Yorùbá kì í kó ipa kankan nínu ix} àgb| tàbí nínu èto pípèsè oúnjc. Lóòót< ni Lóòót< k<
6. Ìgbàgb< àwvn Yorùbá nígbà kan rí ni wípé ó ní ojú ix} tí àwvn obìnrin lè xe. Lóòót< ni Lóòót< k<
7. Àkókò zlàjú tètè yí ìgbàgb< àwvn Yorùbá ígbà kan rí yí padà. Lóòót< ni Lóòót< k<
8. Gbogbo enìyàn k< ni ó gbàgb< nígbà kan rí pé àwvn ix} kan náà wà tí kò yc kí obìnrin xe. Lóòót< ni Lóòót< k<

9. Àwvn ix} òde òní bíi ix} vl<pàá àti ix} panápaná ni gbogbo enìyàn kà sí ix} vkùnrin.

Lóòót< ni Lóòót< k<
10. L<w<l<w< báyìí, kò sí ix} tí vmvbìnrin ní l<kàn pé oún f} xe tí ààyè kò sí fún un. Lóòót< ni Lóòót< k<


© African Studies Institute, University of Georgia.