Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 17: > Lesson 1: Awvn vl<pàá n wá àwvn adigunjalè mcrin
 
    

Awvn vl<pàá n wá àwvn adigunjalè m}rin.

Oníròyìn:              C káàsán o
                            Eyí ni iròyìn ní xókí
                            Emi, Olátúnbzsún Zj}labí ni oníròyìn yín.

 

Awvn vl<pàá n wá àwvn adigunjalè m}rin.
Zgá àwvn Vl<pa ní Ipínl| yí, Vmvvba Adéycyc fi ipé jade nípa àwvn adigunjalè m}rin tí àwvn vl<zpá n wá káàkiri ìpínl| yí. O xe ìkéde yí nínu ìpàdé tí ó ní p|lú àwvn oníròyìn ní Iyaganku ní zsán yí. Vmvvba Adéycyc xàlàyé pé vmv ìyá ni méjì nínu àwvn olóxa wznyí. Awvn méjèèjì yí nìkan sì ni àwvn vl<zpá ní àpèjúwe wvn l<w<. Eyí tí ó j} |gb<n dúdú, ó xe figb<ràn, ó sì ga bí iwzn cs| bàtà m}fà. Kò ní irunmú tàbí irùgbzn xùgb<n ó ní àpá zbc nlá kan ní |r|k} r| láb} ojú ztún. Abúrò olóxà yí j} enìyàn kúkurú ní tir|. O ga bí cs| bàtà márun ààbz, ó sì m<ra. G}g} bí wvn xe xàpèjúwè r|, ó ní irùgbzn kíkún àti irunmú kékeré. Yàtz sí àwvn t|gb<n tàbúrò olóxà yí, vgá vl<pa fit ó àwvn oníròyìn létí pé àwvn adigunjalè méjì yókù j} vkùnrin kan àti obìnrin kan. Bí ó til| wipe àwvn Vl<zpá kò ní àpèjúwe àwvn méjì wznyí, ìgbàgb< àwvn Vl<zpá ni wipe w<n j} vmv ìpínl| yí xùgb<n tí w<n gb< ède Yorùbá, Haúsá àti Igbò. L}yìn ìgbà tí ó pín ìwé ìxàpèjúwe àwvn olóxa wznyí, Vmvvba Adéycyc rv àwvn ará ìlú tí ó bá mv ohunkóhun nípa àwvn enìyàn burúkú wznyí láti tètè ké sí àwvn Vl<zpá nítòsí wvn. Eyí ni iròyìn ní xókí. C dara pz m< wa ní aago méje alé yi fún iròyìn l}kunr}r}. Olátúnbzsún Vj}labí ni ó tí n ròyìn fún yín. Iyókù dìrzl}, lágbára Vl<run. O dìgbà kan na.