Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 17: > Lesson 3: Àxè ìgbeyàwó vmv Olóyè Mákindé.
 




    

Axe ìgbéyàwó vmv Olóyè Mákindé.

Mo ti bá wvn dé ibi aycyc tí ó lárinrin rí xùgb<n n kò rò pé cnik}ni ní ìlú Jóbèlè ti rí aycyc tí ó dùn yùngbà yùngbà tó ti àxe ìgbeyàwó vmv Gb<baníyì ti ìlú Jóbèlè, Olóyè Oyèwálé Mákindé. Iròyìn kò tó àfojúbà. Ináwó nlá ni w<n xe ní vj< tí wvn n fi vmv f<kv yìí. Láti ilé toko ni àwvn àlejò ti wá. Àwvn ènìyàn wá láti ìtòsí bí i Ìlvrà, Fìdítì, Akínmz<rìn, Awé títí dé Zy<. Àwvn míràn sì wá láti znà jíjìn bí i Ìbàdàn àti Èkó. Zpz àwvn af}nif}re tí w<n bá cbí vkv wá dána láti Ògbómzx< náà ni w<n sì gbìyànjú, tí w<n náwó nára. Gbogbo ètò tí w<n xe l<j< náà ni ó gbayì xùgb<n àxeyc ti ìrzl} níbi tí àwvn eléré ti xeré ni ó ga jù. Oúnjc oríxiríxi ni w<n xètò. W<n gún iyán, w<n rokà, w<n se ìrcsì, kódà àwvn vmv agbo ilée  Mákindé tún ro láfún rcpctc. Irú vb| tí ó bá sì wu oníkálukú ni ó lè fi jcun. W<n se àbùlà gb|gìrì àti ewédú, w<n ro òxíkí, w<n se ilá lásán àti ilá àsèpz. Kódà, àwvn cgb} ìyàwó tún pèsè |f< rírò p|lú edé àti cja gbígbc. N ò rò pé irú cran kan wà tí wvn kò xe ní vj< yí. Yàtz sí màálù márùn-ún tí w<n pa, w<n ti se cja tútù, adìyc, panla, ògúnfe àti oríxiríxi cran ìgb}. Ìgbín díndín àti vb| ata náà sì tún wà rcpctc. Yàtz sí oúnjc, vkz cl}rù ni w<n fi xètò ike omi tútù wá láti Ibàdàn. Àgbá omi tútù nlá m}rin sì ni Olóyè Mákindé ti gbà láti Owódé p|lú yínyìn nínúu wvn. Oríxiríxi ohun mímu ni w<n kó sínú àwvn àgbá wznyí. Àwvn vtí cl}rìndòdò bí i kóòkì, fántà, àti b}| b}| lv wà níb| rcpctc. W<n tún kó vtí bíà oríxiríxi náà síb| bí i sítàà, gúdà, sítáùtù àti tírí-tirì. Gbogbo ènìyàn tí ó wá síbi àxè ìgbéyàwó yí ni w<n jc, ni w<n mu, tí w<n yó bámúbámú.