Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 17: > Lesson 4: Àdúgbò Tèmídire ní ìlú Adó ÈKìtì




    

Àdúgbò Tèmídire ní ìlú Adó ÈKìtì.

Àdùk}: Mo ti gb< nípa oríxiríxi àdúgbò dáradára ní il| Yorùbá xùgb<n kò sí àdúgbò tí ó wú ni lórí tó Àdúgbò Tèmídire níìlú Adó Èkìtì. Àdúgbò yí ni mò n gbé nísìsìyí. Àdúgbò yíi tóbi púpz. Agbo-ilé tí ó wà ní àdúgbò yìí tó ogójì. Orúkv olórí àdúgbò yìí ní Olóyè Adéwálé Dàda. Títì vl<dà mcrin ni ó gba àdúgbò yíí kvjá. Ilé-ìwé alákvb}r} kan àti Gíràmà kan ni ó wà ní `adúgbò yìí. Ilé-ìj<sìn àwvn onít|bomi àti t àwvn Ajéri Jìhófà wà níb| p|lú. A tún ní m<xáláxí kan fún àwvn mùsùlùmí. Àwvn vmv àdúgbò wa f}ràn eré púpz. W<n ma n xe zpzlvpz eré ìdárayá ní ìrzl} vj< àìkú. A kò ní ilé àwvn vl<pa nítorí pé kò sí adigunjal| tàbí zdaran kankan ní àdúgbò wa. Àwvn aládúgbò wá j} àsan vmvlúwàbí. Àwvn cbí tí ó wà ní àdúgbò maá n ran ara wvn l<w<. Kódà, cbí kzzkan ni ó gbé kanga sí iwájú ilé wvn. Ìrànl<w< àwvn mzl}bí àti aládúgbò ni èyí xe xe é xe. Ìpàdé àdúgbò àti Olóyè Dàda ni w<n xe |tv kanga gbígbé fún àwvn ìdílé tí kò ní agbára fún ìnáwó kanga. Àwvn ìdílé míràn ní owó dí|, w<n sì ní |rv amóhùnmáwòrán àti |rv rédíò. Olóyè àdúgbò yìí f}ràn àwvn enìyàn àdúgbò r| l<pzlvpz. Ó ma n pa cran fún wvn ní àkókò vdún. Àwvn vmv àdúgbò bí i m}wa tí àwvn òbí wvn kò lówó l<w< ni ó n rán lv sí ilé=ìwé. Àdúgbò wa ni ó gbayì jù ní Adó-Èkìtì. Àdúgbò wa ni a ti yàn Gómínà ìpínl| Èkìtì tí ó kvjá. Àwvn ará àdúgbò yìí f}ràn ara wvn. Àwvn zd< àdúgbò ni ó má n gé vkz ojú znà tí ó bá ti kún.