|
Ixc Òòjó fún àwvn
Obìnrin
B<látitó: Ní inú àxà ìbíl|
Yorùbá, ààyé wà fún
obìnrin láti xe zpzlvpz ix} òòjó.
Awvn Yorùbá kò gbàgb< pé ìpín àwvn
obìnrin ni láti jókó sílé,
kí w<n sì máa xe ìt<jù ilé àti àwvn
vmv nìkan. Àwvn obìnrin ní oríxii
ix} tí w<n maá n xe g}g} bí vjà títà,
axv híhun, ap|r| híhun, irun dídì,
aró dídá, oúnjc sísè tà,
ix} alágbo vmv, ix} agbèbì àti àwvn
ix} oríxiríxi míràn. Yàtz sí àwvn
ix} wznyí, àwvn obinrin nínu àxà ìbíl|
Yorùbá tún maá n kó ipa títóbi
nínu ix} àgb|. W<n xe pàtàkì púpz
nínu èètò pípèsè oúnjc,
yálà nípa reran àwvn vkv wvn l<w< nínu
oko tàbí nípa dídá oko etilé kékéèké.
Bí ó til| j} wipe àwvn obìnrin lè xe
ix} òòjó oríxiríxi nínu àxà ìbíl|
Yorùbá, àwvn ix} kan wà tí Yorùbá gbàgb< pé obìnrin
kò lè xe. Àwvn ix} bíi ix} vdc, ix}
eyín tàbí opé kíkv, ix} pcjapcja,
ix} ológun àti àwvn ix} alágbára
míràn wà lára àwvn èyí tí Yorùbá kò gbàgb< pé obìnrin
lè xe. Bí ó tilc j} wipe a lè rí ap|r| àwvn
akínkanju obìnrin tí w<n n fí àwvn
ix} wznyí xe ixc òòj<, ìgbàgb< àwvn
Yorùbá kò yè pé àwvn
ix} bí i àwvn wznyí kì i xe ix} obìnrin.
Nígbà kan rí, ó nó ojú ix}
tí àwvn Yorùbá gbàgb< pé obìnrin
lè xe. Àkókò zlàjú kò tètè yí ìgbàgb< yí padà.
Kódà, àwvn ix} òde òní kan
náà tún wà tí gbogbo enìyàn
gbàgb< nígbà kan rí, pé kò yc
kí obìnrin xe. Àwvn ix} òde òní bíi
ix} adáj<, amòfin, ix} vl<pàá,
ix} panápaná, ix} agbáb<zlù àti
ix} d<kítà ni w<n kà sí ix} vkùnrin. Àwvn
ix} bíi ix} n<zsì, ix} at|wé, ix} olúk< àti
ix} vjà títà ni w<n sì kà sí ix}
obìnrin. Ìgbàgb< yí dá lórí àxà reran
vmvkùnrin nìkan lv sí ilé ìwé.
Axà yí ti n kas| níl| nísisìyí xùgb<n
zpz àwvn ak}kz< l<kùnrin àti lóbìnrin
ní w<n ní láti lv gba ìmzràn
pé kò sí ix} tí w<n f} xe ti wvn
kò leè xe é xe, yálà ix} ìbíl|
tàbí ix} òde òní. Ìgbà n
yí, à n tz < ni zrz ix} òòj< fún àwvn
Obìnrin ní il| Yorùbá jc. L<w<l<w< báyìí,
kò sí ix} tí vmvbìnrin ní l<kàn
pé oún f} xe tí ààyè kò sí fún
un. Àwvn obìnrin ní il| Yorùbá ti
n dí zgà l}nu oríxiríxi ix}, pàápàá jùlv
l}nu àwvn ix} tí a tí n sv t}l| pé,
obìnrin ò lè xe. |
|
|