Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 17: > Lesson 6: Àwvn Ilé Ck< tí mv lv
    

Àwvn Ilé Ck< tí mv lv.

Cnjinia Ògúnjìmí: Vmv vdún m}ta àti àbz ni mí nígbà tí mo b|r| ilé-ìwé. Ilé ìwé j}léósinmi ni mo k<k< lv. Olùk< wa ni yóò wá mú èmi àti àwvn clcgb} mi ní agogo m}jv àbz àárz. Màmá mi á ti lv sí vjà wvn. Àwa vmv kékeré bí i m}|d<gbzn ni olùk< yí ma n kó l}yìn lv sí ilé-ìwé yì í. Mo b|r| ilé-|k< alák<b|r| nígbà tí mo di vmv vdún m}fà. Ilé ìwé alák<b|r|  ìjv onít|bvmi ti Idikan, Ìbàdàn ni mo lv. Vdun m}fà ni mo lò ní ilé-|k< yìí. Àwvn olùk< wa f|ràn mi nítorí pé mo mv ìwé púpz. Ipò mi kì í ju ipò kínní sí ìkcrin lv fún vdún m}fà tí mo lò ní ilé ìwé yì í. C}mcta l<dún ni a má n xe ìdánwò. Ìdánwò k}ta sì j} àxekagbà. Èyí ni ó j} kí a t| síwájú lv sí kíláàsì míràn. L}yìn vdún kcfà, a xe ìdánwò àxejáde ní ilé-wé alákvb|r|. Mo tún xe ìdánwò sí zpzlvpz àwvn ilé-ìwé gíga. Nígbà tí èsì ìdánwò dé, mo yege. Àwvn ilé-ìwé gíga m}ta ni ó kv ìwé sí mi pé àwvn gbà mí. Baba mí f} kí n lv sí ilé-|k< onígbàgb<.
Èyí ni ó j} kí n lv sí ilé|k< Lòyólà ní Ìbàdàn. Ìjv Àgùdà ni ó ní. Vdún m}fà ni mo lò ní ilé-ìwé yìí. Àwvn ix} bí m}tàlá ni mo xe. L}yìn vdún m}ta àk<k<, mo xe ìdánwò. Mo sì yege. Mo tún b}r} vdún m}ta èkejì. Awvn |k< tí ó jc m< sáy}nsì ni mo xe. Nígbà tí a xe ìdánwò àxekagbà ti WASC àti NECO. Mo yege nínu |k< m}sàn-án tí mo xe. Ilé-ìwé gíga Yunifásítì ti Ìbàdàn ni mo lv. Ck< nípa ìmv ìjinl| èrò ni mo xe. Vdún márùn-ún ni mo lò. L}yìn vdún kcrin, àwvn olùk< wá gbà wá láàyè láti lv fojúsí |k< yìí ní àwvn ilé-ix} nlánlá. Oxù m}fà ni mo lò. Ilé ix} Julius Berger ni mo lv. L}yìn tí a xe tán, mo ti lè dá ilé k< fúnra mi. L}yìn vdún karùn-ún, mo xe ìdánwò àxekágbà, mo sì yege. Mo lo vdún kan g}g} bí agùnbánirz ní ilé-ix} tí ó n xètò ilé gbígbé ti ìjvba àpapz ní ìlú Minna. Mo xe oríire pé l}yìn ètò agùnbánirz mi, mo rí ix} ní ilé ix} Julius Berger ní Èkó g}g} bí zgá ní |kà ix} èrò ibi ix} náà. Nísisìyí, mo n rí èrè àwvn ilé |k< tí mo lv.