1. Púpz lára àwvn
aycyc nínú u àxa Yorùbá. wznyí ni
w<n kò so m< oríxiríxi ipò |dá láàrin àwùjv. |
Lóòótv
ni |
Lóòótv
k< |
2. Àwvn Yorùbá gbàgb< pé gbogbo àw<n
aycyc w<n ni wvn xe pàtàkì. |
Lóòótv
ni |
Lóòótv
k< |
3. Àkókò àwvn
oríxiríxi aycyc wznyí lè j| àkókò àjvyz
tàbí àkókò ìbànúj} àti ìbánik}dùn. |
Lóòótv
ni |
Lóòótv
k< |
4. Àwvn aycyc wznyí kò wúlo
nítorípé w<n kì í mú àjvxe
wà láàrin àwvn mzl}bí àti àwvn
aládúgbò. |
Lóòótv
ni |
Lóòótv
k< |
5. G}g}bí ìgbàgb< àwvn
Yorùbá, ó y} kí á bá àwvn
tí wvn bá n yz, yz, kí á sì bá àwvn
tí w<n bá n svkún, svkún. |
Lóòótv
ni |
Lóòótv
k< |
6. Àwvn vdún ìbíl|
kì í j} kí àwvn Yorùbá ní ànfàní láti
gbé àxa, ìxe àti |sin w<n lárugc. |
Lóòótv
ni |
Lóòótv
k< |
7. Àyípadà oríxiríxi
ti dé bá gbogbo àwvn
aycyc tí àwvn Yorùbá máa n xe
nítori zlàjú àti àwvn |sìn àjòjì tí o
ti wv il| Yorùbá |
Lóòótv
ni |
Lóòótv
k< |
8. Zpzlvpz àwvn vmv bíbí il|
Yorùbá ni
kò gbéyàwó tàbí svmvlórúkv
g}g} bí axa ìbíl| Yorùbá mv. |
Lóòótv
ni |
Lóòótv
k< |