1. Baálé cbí ni ó mojútó (to
oversee) gbogbo ìpal|m< fún èto ìsvmvlórúkv
yì í. |
Lóòótv
ni |
Lóòótv
k< |
2. Bàbá vmv tuntun
ni o gbé vmv l<w< ní àkókò ìpal|m< fún èto ìsvmvlórúkv
yì í. |
Lóòótv
ni |
Lóòótv
k< |
3. Àwvn cbí àti
zr} ni w<n péjv (to gather) fún aycyc ìsvmvlórúkv
yì í. |
Lóòótv
ni |
Lóòótv
k< |
4. Gbogbo ohun ti wvn yóò nílò fún èto ìsvmvlórúkv
ni o pe. |
Lóòótv
ni |
Lóòótv
k< |
5. Baálé kò gba àdúrà (prayers)
fún gbogbo àwvn cbí àti zr} tí w<n
wá fún aycyc ìsvmvlórúkv yì í. |
Lóòótv
ni |
Lóòótv
k< |
6. Gbogbo àwvn cbí àti
zr} ni wvn xe (to respond) àxc sí gbogbo àdúrà (prayers)
tí Baálé gbà. |
Lóòótv
ni |
Lóòótv
k< |
7. Ìyá àgbà k< ni
o dá orin ‘Kúlúmbú ycyc’ |
Lóòótv
ni |
Lóòótv
k< |
8. Omi, atare, iyz, orógbó,
obì àti epo j} dí| lára àwvn
nnkan àdúrà tí àwvn Yorùbá máa
n lò fún èto ìsvmvlórúkv. |
Lóòótv
ni |
Lóòótv
k< |
9. Àkókò àjvyz
ni aycyc ìsvmvlórúkv
yì í j| fun àwvn òbí p|lú gbogbo àwvn
cbí àti zr} |
Lóòótv
ni |
Lóòótv
k< |
10. Oyin, àádùn, cja,
irú àti ìrèké kò sí lára àwvn
nnkan àdúrà tí àwvn Yorùbá máa
n lò fún èto ìsvmvlórúkv. |
Lóòótv
ni |
Lóòótv
k< |