Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 18:ÀWVN ORÍXÌÍ ÀYCYC > Lesson 1: Ìwúlò àwvn oríxìí aycyc ní il| Yorùbá




    

Oríxiríxi aycyc ni ó máa n wáyé nínú u àxa Yorùbá. Púpz lára àwvn aycyc wznyí ni w<n so m< oríxiríxi ipò |dá láàrin àwùjv. G}g} bí àwvn aycyc kan xe so m< àkókò tí |dá bá j} ìkókó b}|ni àwon kan so m< ìyípòpadà |dá. Nítorí ìdí èyí, àkókò àwvn aycyc wznyí lè j| àkókò àjvyz tàbí àkókò ìbànúj} àti ìbánik}dùn. Kò sí aycyc Yorùbá kankan tí a lè sv wípé kò ní ìtúm<, kódà gbogbo wvn ni àwvn Yorùbá gbàgb< pé w<n xe pàtàkì. Dí| lára àwvn oríxiríxi aycyc wznyi ni ìsvmvlórúkv tàbí ìkómvjáde, ìgbeyàwó, ìxílé, orísirísi vdún ìbíl|, ìfinijoyè tàbí ìwúyè, ìsìnkú àgbà àti ìjáde òkú. Àwvn aycyc wznyí wúlo fún oríxiríxi nnkan. Ní àk<k<, ànfàní nlá ni w<n j} fún cbí àti ìyekan láti kó ara wvn jv. Bí bára cni xe báyìí kì í j} kí iná ìf} tí ó wà láàrin cbí jó àjór|yìn. Àwvn mzl}bí láti ìtòsí tàbí láti znà jíjìn yóo máa lè fi ojú kojú lóòrè kóòrè níbi àwvn aycyc wznyí.

Yàtz sí àjvxe laarin àwvn mzl}bí, àkókò àwvn aycyc wznyí tún j} àkókò fún àwvn aládúgbò láti kópa pàtàkì nínú ìgbé ayé araawvn. Ìgbàgb< àwvn Yorùbá ni wípé ó y} kí á bá àwvn tí wvn bá n yz, yz, kí á sì bá àwvn tí w<n bá n svkún, svkún. Ìwúrí ni ó máa n j} fún àwvn tí ó n xe aycyc láti rí àtìl}yìn gbogbo cbí, zr} àti ènìyàn láwùjv tí w<n péjv fún aycyc yì í. Àwvn aycyc míràn til| j} àwvn èyí tí gbogbo ará ìlú ní láti kópa láti orí àwvn l<bal<ba àti àwvn ènìyàn jànkànjànkàn títí dé orí àwvn m|kúnnù. Àwvn vdún ìbíl| wznyí máa n fún àwvn Yorùbá ní ànfàní láti gbé àxa, ìxe àti |sin w<n lárugc. Àp|crc irú àwvn aycyc báyìí ní vdún zsun Òxogbo ní ìlú Òxogbo àti vdún ojúde vba láàrin àwvn Ìj|bú. Nípas| zlàjú àti àwvn |sìn àjòjì tí o ti wv il| Yorùbá, àyípadà oríxiríxi ni ó ti dé bá gbogbo àwvn oríxiríxi aycyc tí àwvn Yorùbá máa n xe. Zpzlvpz àwvn vmv bíbí il| Yorùbá ni kò gbéyàwó tàbí svmvlórúkv g}g} bí axa ìbíl| Yorùbá mv. Ayé n yí à n tz <!

Sinima kékeré òkè yì í (the above short video) ní àpcrc akítiyan àwvn vmv káàárz o ò jíire láti xe ìgbeyàwó wvn ní ìlànà ìbíl| bí ó til| j| wípé cl}sìn ìgbàgb< (ti vmv |yin Jeésù ni wvn j}).


© African Studies Institute, University of Georgia.