Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 18:ÀWVN ORÍXÌÍ ÀYCYCI > Lesson 2: Àxàyàn Ìkíni àti Àdúrà níbi oríxiríxi aycyc




    

 

 

 

AYCYC

(Ceremony)

CNI TÍ À N KÍ

(the people to greet)

&

SÍSV NÍPA AYCYC (talking about ceremony)

 

 

ÀXÀYÀN ÌKÍNI ÀTI ÀDÚRÀ

(selected greetings and prayers)

 

 

Ìsvmvlórúkv

/ Ìkómvjáde

 

(Naming Ceremony)

 

Àwvn òbí ìkókó/

Bàbá àti ìyá vmv tuntun

 

 

 

Àwvn zrz ìxe (verbs):

- svmvlórúkv

- kómvjáde

 

- xe (aycyc) ìsvmvlórúkv

- xe (aycyc) ìkómvjáde

 

Ìkíni:

- C kú àyv ìkómvjáde

- C kú ìjáde òní

- Mo yz fún ún yín o

- C kú oríire o

 

Àdúrà:

- A j} orúkv kal} o

- Èdùmàrè á ka kún wa o

- A á tó àwvn olórúkv r|, a jù w<n lv o

- Vl<run á kà á kún wa o

 

Ìgbeyàwó

 

(Marriage Ceremony)

 

 

Vkv àti ìyàwó tuntun

 

 

 

Àwvn zrz ìxe (verbs):

- gbéyàwó

- xe (aycyc) ìgbeyàwó

 

Ìkíni:

- C kú ìnáwó ìyàwó

- C kú àxeyc òni o

- C kú ìk} ìyàwó o

- C kú oríire o

 

Àdúrà:

- Cyìn ìyàwó kò ní mcní

- Olúwa á j} k}c rí érè níb| o

- Ohun tí c fi n wu ara yín kò ní xá o

- Olúwa á xe yín ní zr} ara yín o

- C } tvw< bv osun fi pa vmv lára

- Àníkún owó, Àníkún vmv nÍlé yín o

 

Ìxílé

 

(House warming Ceremony)

 

Cni tí ó n xílé tuntun

 

 

Àwvn zrz ìxe (verbs):

- xílé

- xe (aycyc) ìxílé

 

Ìkíni:

- C kú ìxílé

- C kú ìnáwó ilé yì í o

- C kú oríire o

 

Àdúrà:

- Ilé (yì í) á tu ra o

- Ojú burúkú, cs| burúkú kò ní wz < o

- C ò ní ru òkú vmvdé wvlé, ru òkú vmvdé jáde ní ilé yì í o.

- C ó fi xíl| fún vmv

 

 

Ìwúyè

 

(Chieftaincy Ceremony)

 

Olóyè tuntun

 

 

Àwvn zrz ìxe (verbs):

- joyè

- wúyè

- xe (aycyc) ìwúyè

Ìkíni:

- C kú ìnáwó oyè

- C kú oríire o

 

Àdúrà:

- Oyè á m<rí o

- C ó fi oyè náà xe rere

- Ewé oyè á p} lóri o

- Cmí á lo ó p}

 

 

Ìsìnkú àgbà

 

(Funeral for an elderly person)

 

 

Vmv Olóòkú

 

 

Àwvn zrz ìxe (verbs):

- xìnkú

- xe òkú / xòkú

- xe (aycyc) ìsìnkú

 

Ìkíni:

- C kú às|hìndè

- C kú oríire p}l}hìn kò xíwájú lv

- C kú ará f} ra kù

 

Àdúrà:

- Cyin wvn á dára o

- Vmv rere á gb|yìn àwa náà o

- Olúwa ko ní xe ni àkú fà o

- C kú àmúléró

 

 


© African Studies Institute, University of Georgia.