Baálé: Tv z, Abí<dún Akínkúnmi
vmv Adéwálé,
Omi
ayé ré o, omi ayé ré o, Kò ní pá v lórí o
Baálé: Odo o ni gbe v lv o
Baálé: To ba ti n mumi bayi, yo ma tu o lara
ni
To
ba n fomi we, yo tu o lara
Baálé: Omi ayé ò ní gbé v lv
Baálé: B} | ni yí ò rí o
lágbára àwvn
babanlá wa
Baálé: Abí<dún Akínkúnmi vmv Adéwálé,
Oyin
ayé ré yí ó, yo má a dùn m< v l}nu ni ò
Baálé: Ládùn ládùn lá b’óyin
Ládùn
ládùn lá b’óyin
Baba: Gbogbo ìgbésí ayé rc
yí ó ma à dùn ni.
Baálé: Yí ó ma à dun fún o ni
Baálé: Bv bá wà l’àárín cgb}, yí ó dùn fún v
Baálé: Bv bá wà l’àárín zgbà, yí ó dùn
fún v
Baálé: Làárín ebí yí ó dùn fún v ni
Baálé: B}|ni ó rìí o
Baálé: Àádùn ré o, yí ó má a dùn fún v ni
Baálé: Didun didun la ba’le oloyin
Baálé: Dídùn
dídùn là szrz àádùn,
yí ó má a
dùn fún v ni
Baálé: Nínú cgb} yí ó má a dùn fún
v ni
Baálé: L’aarin zr} yí ó má a dùn fún
v ni
Baálé: Obí rè é o.
Obì níí bikú, obì níí bàrùn
Obì i náà ní bc àwvn àgbà olójú kìnìún
Kìnìún. Obì nì í o, obì nì o, obì
O ò ní kú,
Baálé: O ò ní rùn
Baálé: Obì yí ò bi’kú dànù fún v
Baálé: Obì yí ò bi àrùn dànù fún v
Baálé: Gboqo bi v bá dé láyé yìí,
obì yìí ma n
qayì ni, < maa
qayì
Baálé: Oróqó rè é o, O ó qò ó
Baálé: V v tz<
Baálé: > f’vw< páwú
Baálé: Ó tùn ún f’èrìgì jobì
Baálé: B} | ni yó rì í o
Atare
ré o, kìí di ti | láàb<.
Níre, níre làá szrz atare,
qoqo ibi o bá wà, ire ni w<n ó mv fi lz <
Baálé: Ayé ò ní bínú rc
Baálé: Zta ò ní bínú rc
Baálé: O ó ma borí ztá ni
Baálé: B} | ni ó rìí
Baálé: Irú rè é o, yó jú v < xe
Baálé: Zrz rc ò ní burú
Baálé: O ò ni…, gboqo ìqésí ayé rc,
búburú kan ò ní bá v
Baálé: Ayz, ayz ni tì c o má a jc
Baálé: Iyz rè é o
Ládùn
ládùn làá szrz iyz
Zrz rc o má a dùn ni
Baálé: Zrz rc o má a dùn ni
Zrz rc o má a dùn ni
Zrz rc o má a dùn ni
Baálé: Ìrèké rè é,
Dídùn
làá bá dùn ìrèké o
Zrz rc ò ní burú o
Baálé: Ní qoqo znà rc
qoqo ibi tv bá wà láyé yìí,
Zrz rc o má a dùn ni
Mzl}bí: Àxc wà á ni tìrèké!!
Baálé: Cja rè é o,
Orí lcjá fií labú,
Orí làkàtà fií la ti | lódò
Orí rc kò ní burú
Baálé: Gboqo ibi o bá wà láyé yi
Znà ó mà a
là fun v ni
Baálé: Znà rc ò ní dí
Baálé: Gboqo cni bá dojú ztá kv <,
pátápátá orí ax}ta lo mú wúyé,
> má a
s}gun wvn ni
Baálé: B} | ni ó rìí
Baálé: Ó sì ti rí b}|
Baálé: Láqára àwvn baba nlá wa
Baálé: Mo rò pé qoqo náà lati fi i..;
ah! ó kepo o!
Vm< p<n
l’orúkv tí < n pe epo.
Baálé: Gboqo zrz rc, ní qoqo ibi o bá dé
ó má a
p<n ni ò
Baálé: Ó mán l} pzn <n ni
Baálé: Ó mán l} pzn <n ni
Baálé: L’aarin cqe ó l} pzn <n
Baálé: L’àárín cbí ó l} pzn <n
Baálé: Níqà o bá dàqà tó n rín, tó n sáré s<un,
tó n
sáré síhín, ayé ò ní kv < l}s|
Baálé: Òòr|, ní qoqo ayé rc, |pvn ló má a ní Baálé: O ó sì ga
ju àwvn cq} rc lv
Baálé: Hcn, Kúlúmbú ycyc….
(wvn
dá orin / leads the singing):
Gbogbo }bí:
zycyc kúlúmbú,
a ó f’ztún gb<mv
jó
Kúlúmbú ycyc, zycyc
kúlúmbú,
a ó f’òsì gb<mv
pzn
Kúlúmbú ycyc zycyc
kúlúmbú.
a ó xòwò tó lerè o
Kúlúmbú ycyc zycyc
kúlúmbú.
|