A. Dí| lára àwvn zrz tí o so mv ìlera (some health related
words):
Ède Yorùbá
|
English
|
|
Ède Yorùbá
|
English
|
Ilé ìwòsàn
|
Hospital
|
|
Aláìsàn
|
Patient
|
Yàrá aláìsàn
|
Ward
|
|
D<kítà / oníxègùn
|
Doctor (Md)
|
Káàdì
|
Card
|
|
Nóòsì
|
Nurse
|
Ìwé ìgboògùn
|
Prescription
|
|
Olùt<jú aláìsàn
|
Hospital worker
|
Oògùn
|
Medicine
|
|
Apòògùn
|
Pharmacist
|
Oògùn oníwóró
|
Tablet/Capsule
|
|
D<kítà Oníx}-abc
|
Surgeon
|
Oògùn alátíkè
|
Powdered medication
|
|
Ìlera / ara yíyá
|
Health
|
Oògùn olómi
|
Syrup
|
|
Àìsàn / Àìlera
|
Illness / Ailment
|
Abéré
|
Injection
|
|
Ìt<jú : t<jú
|
Care : to care for
|
dùn (dídùn)
|
to hurt or pain (hurting)
|
|
ro (ríro)
|
to ache (aching)
|
Run (rírun)
|
to hurt (stomach)
|
|
f< (fífz)
|
to ache (head)
|
Ní / mú (mímú)
|
to have/catch disease
|
|
lò
|
to use
|
Gbà
|
to receive
|
|
mu
|
to drink
|
B. Dí| lára àwvn àìlera àti
xíxe àlàyé nípa wvn (some ailments and expressions):
English
|
Àìlera (ailment)
|
Xíxe Àlàyé (expression)
|
Body ache
|
Ara ríro
|
Ara n ro mi
|
Hurting back
|
Cyìn dídùn
|
Cyìn n dùn mí
|
Upset stomach
|
Inú rírun
|
Inú n run mí
|
Stomach ache
|
Inu riro
|
Inú n ro mí
|
Headache
|
Orí fífó
|
Orí n f< mi
|
Malaria/Fever/Flu
|
Ibà
|
Ibà n mú mi / Ibà n xe mi
|
Cold/chill
|
Òtútù
|
Otútù n mú mi
|
Cold w/sinus
|
Zfìnkìn
|
Zfìnkìn n xe mi
|
Cough
|
Ik<
|
Mò n húk< / wúk< / Ik< n hú mi
|
High temperature
|
Ìgbóná
|
Ara mi n gbóná
|
Illness / tiredness
|
Aìsàn (xe aisan/
x’àìsàn)
Àár| (xe àár|/
sàár|)
|
Ó n xe àìsàn
/ àìsàn n xe é!
Ara mi ko ya
Ó r| mí / Àár| n mú mi
|