|  
             
               
              
               
               
           
                   
               
           | 
          Lesson 1:	Ilé Alájà Méjì ni ilé àwvn Y}misí ní Cdc. 
          
         Vmvlará: 	 	 	 
         Zr} tím<tím< ni èmi àti Y}misí.  
         O sì f} kí n wá mv cbí òun. 
         Mo pinnú láti bá a lv ní ìsinmi kérésìmesì tí ó kvjá.  
              Ilé alájà méjì ni
                ilé àwvn Y}misí ni Cdc ní ìpínl| Zxun.  
              Zdà aláwz ewé ni w<n fi kun gbogbo ìta ilé yì í.  
              Xùgb<n awz olómi vsàn ni àwvn fèrèsè r|.  
              Yàrá m}fà ni ó wà ní òkè àti ìsàl| ilé yí.  
              Nígbà tí a wvlé, ó mú mí gun òkè lv.  
              Mo ri pé àwvn ayálégbé ni
                w<n n gbé gbogbo yàrá ìsàl|. 
              Y}misí àti àwvn cbí r| sì n lo gbogbo yàrá m}f||fà lókè. 
              Ilé Ìdáná nlá kzzkan wà lókè àti nísàl| ilé yí. 
              Ilé-ìw| àti ilé ìgbzns| kzzkan
                sì tún wà ní òkè àti ìsàl|. 
Baba Y}misí ni ó ni yàrá kinni lókè.  
Ìyàwó méjì ni bàbá Y}misí ní, ìyàwó kzzkan sì ní yàrá tir|.  
Y}misí àti àwvn àbúrò r} obìnrin méjì ni w<n jv n sun yàrá kan. 
Àwvn vmvkùnrin méjì yóókù sì n sun yàrá karùn-ún 
Yàrá kcfà ni w<n fi n xe yàrá igbàlejò.  
                    | 
         
       
 |