Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 15: Ix} Olùk<> Exercise 5:

Exercise 5:    Based on lesson 5, select the answer from the three provided for each of these questions:

        1. Kí ni ó ya àwvn olùk< Yunifasiti ati ile olukoni soto?

        A. Zpz ló j} vkùnrin àti obìrin
         
        B. Zpz ló n k< vmv ni |k<
         
        D. Zpz ló j} zmzwé
         
         
        2. Vdún mélòó ní cni tí ó bá f} xix} olùk< máa lò láti gba oyè En-siì?

        A. Vdún m}ta
         
        B. Vdún méjì
         
        D. Vdún m}rin
         
         
        3. Bí ó til| j} wípé ix} olùkvni kò lówó lórí púpz, o ní

        A. Íyì ní àwùjv
         
        B. Ìdí ní àwùjv
         
        D. Zgá ní àwùjv
         
         
        4. Níbo ni enìyàn náà lè lv sí tààràtà l}yìn ilé-|k< gírámà láti kv ix} olùkvni?

        A. Ilé-ìwé olùkvni
         
        B. ilé-|k< gírámà.
         
        D. Yunifásítì
         
         
        5. Zkan lára àwvn ix} oòj< tí ó xe pàtàkì jùlv ni ________________

        A. Ix} Olùk<
         
        B. Ix} Zlc
         
        D. Ix} Òpè
         
         
        6. Àwvn wo ni olùk<?

        A. Àwvn tí ó n k< vmv ní |k< ní ilé-ìwé
         
        B. Àwvn tí ó n fún vmv ní |kv ní ilé-oúnjc
         
        D. Àwvn tí ó n rí vmv ní |kv ní ilé-ix}
         
         
        7. Xé Vkùnrin àti obìnrin ni ó lè xe ix} olùk<?

        A. Ó tì, obìnrin nìkan ni ó lè xe ix} olùk<
         
        B. B}| ni, vkùnrin àti obìnrin ni ó lè xe ix} olùk<
         
        D. B}| ni, vkùnrin ni ó lè xe ix} olùk<
         
         
        8. Xé ix} olùk< fi vkàn enìyàn bal| láwùjv?

        A. B}| ni, ix} yì í fi vkàn enìyàn bal| láwùjv.
         
        B. Ó tì, ix} yì í kò fi vkàn enìyàn bal| láwùjv
         
        D. A kò mv bóyá ix} yì í fi vkàn enìyàn bal| láwùjv
         
         

 

© African Studies Institute, University of Georgia.