Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 16: Ilé ìwé rc tuntun yí dára gbá à. > Exercise 3:

Exercise 3:                 Answer the following questions:
Remember:     ilé ìwé aládání              ‘private school’   Kayode’s school
                        Ilé |k< ìjvba àpapz      ‘Federal government school’  Dàda’s school

        1. Àwvn ak}kz< mélòó ni ó wà ní ilé |kv Káyzdé?

        A. Àwvn ak}kz< bí i cgb|rún m}fà
         
        B. Àwvn ak}kz< bí i cgb|rún m}tàlá
         
        D. Àwvn ak}kz< bí i cgb|rún m}wàá
         
         
        2. Àwvn ak}kz< mélòó ni ó wà ní ilé |kv Dàda?

        A. Àwvn ak}kz< bí i cgb|rún m}fà
         
        B. Àwvn ak}kz< bí i cgb|rún m}tàlá
         
        D. Àwvn ak}kz< bí i cgb|rún m}wàá
         
         
        3. Àwvn olùk< mélòó ni ó wà ní ilé |kv Dàda?

        A. Igba
         
        B. Vg<rùn-ún
         
        D. Z<dúnrún
         
         
        4. Ilé |kv Káyzdé n k<, àwvn olùk< mélòó ni ó wà ní ib|?

        A. Igba
         
        B. Vg<rùn-ún
         
        D. Z<dúnrún
         
         
        5. Irú àwzn ak}kz< wo ni ó wà ní ilé |kv Káyzdé?

        A. Àtvkùnrin àtobìnrin ni ó wà ní ilé ìwé Káyzdé
         
        B. Vkùnrin nìkan ni ó wà ní ilé ìwé Káyzdé
         
        D. Obìnrin nìkan ni ó wà ní ilé ìwé Káyzdé
         
         
        6. Ilé |kv Dàda n k<, iru àwzn ak}kz< wo ni ó wà ní ib|?

        A. Àtvkùnrin àtobìnrin ni ó wà ní ilé ìwé Dàda
         
        B. Vkùnrin nìkan ni ó wà ní ilé ìwé Dàda
         
        D. Obìnrin nìkan ni ó wà ní ilé ìwé Dàda
         
         
        7. Kí ló dé tí gbogbo ak}|k< ni ilé |kv Káyzdé gb<dz gbé nínú vgbà ilé-ìwé?

        A. Nítorípé ilé |k< ìjvba àpapz ni ilé |kv Káyzdé
         
        B. Nítorípé Ilé ni gbogbo ak}|k< ni ilé |kv Káyzdé ti n wá.
         
        D. Nítorípé ilé ìwé aládání ni ilé |kv Káyzdé
         
         
        8. Níbo ní Káyzdé máa gbé?

        A. Ó máa gbé nínú vgbà ilé |k< r|.
         
        B. Ó máa gbé nínú gbzgan ilé |k< r|.
         
        D. Ó máa gbé nínú papa ìxeré ilé |k< r|.
         
         

 

© African Studies Institute, University of Georgia.