Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 16: Iriri mi ni Garaaji Ojota > Exercise 6:

Exercise 6:                 Review lesson 6 and answer the following questions:


        1.Níbo ni Ìdòwú n lv láti Vj<ta ní zs| tí ó kvjá?

        Ó n bz láti ìlu Ìbàdàn.
        Ó n bz láti ìlu Ìbátan .
        Ó n lv sí ìlu Ìbátan
        Ó n lv sí ìlu Ìbàdàn.
        Ó n lv sí ìlú agbèrò
         
        2. Kíni vmvdébìrin náà xe fún bàbá tí o wvlé jóko sí |yin Ìdòwú?

        Ó jókó le bàbá náà l}s|.
        Ó tc bàbá náà l}s| m<l|.
        Ó fa bàbá náà l}s| púpz.
        Ó gbá bàbá náà l}s| kúrò.
        Ó ra bàbá náà l}s| dí|.
         
        3.Kí ló de tí vmvdébìrin xe b|r| sí bú bàbá yìí nínú vkz?

        Ó sv wípé bàbá yìí n pariwo.
        Ó sv wípé bàbá yìí n xzrz.
        Ó sv wípé bàbá yìí ti tètè wvlé jù.
        Vmvdébìrin náà kò ní bàbá nílé
        Vmvdébìrin náà kò ní |k< ilé
         
        4.Kíni wvn fi pa ibi cs| tí ó n dun bàbá náà?

        Cnìkan fi vw< pa á
        Cnìkan fi cnu pa á
        Cnìkan fi òrí pa á
        Cnìkan fi owó pa á
        Cnìkan fi cs| pa á
         
        5.Kíni vmvdébìrin yìí xe fún màmá tí ó fvw< t< <?

        Ó gbá vw< màmá náà dànù.
        Ó mú vw< màmá náà dànù.
        Ó gbé àpo màmá náà síl|.
        Ó gbá ojú màmá náà dànù.
        Ó kí màmá náà pé w<n xe é.
         
        6.Tani vmvdébìrin yì í b|r| sí bú l}yìn tí ó gbá vw< màmá yìí dànù?

        Ìdòwú
        Agbèrò
        Vmvlúwàbí
        Àbíìkz
        Èrò nínú vkz.
         
        7.Kíni agbèrò sv fún vmvdébìrin yì í?

        Ó ní òun kò ní j} kí o jókòó nínú vkz
        Ó ní òun kò ní j} kí o wv vkz náà
        Ó ní òun kò ní j} kí o bú òhun rárá
        Ó ní àwvn èrò inú vkz kò f}ràn èébú
        Ó ní ìwa vmvdébìrin yìí kò dára.
         
        8. Kí ni àwvn èrò inú vkz sv nípa vmvdébìrin yì í?

        Wvn sv wípé vmvbìnrin yìí kò ní |k<-ilé ni.
        Wvn sv wípé bóyá àbíìkz ni vmvbìnrin yìí
        Wvn sv wípé vmvbìnrin yìí j} vmvlúwàbí
        Wvn sv wípé vmvbìnrin yìí kìí xe aláìl}kz rárá.
        Wvn sv wípé bóyá vmvbìnrin yìí yóò bc agbèrò
         

© African Studies Institute, University of Georgia.